Gbogbo ojo kefa osu kerin in ni ayajo ojo ibi Sheikh Ajibade Iyanda Abdul Ganiy Adekunle Akewusola Olohun nidahun adura,oludasile ijo istijabah D'uah kaakiri agbaye ati alase ileese Asofam kaakiri orile ede yii,ohun to tun je ki ayeye ojo ibi alaanu awon mekunnu yii yato ni pe,ojo kanna an loun ati akobi re Alaaja Sofiat Ajibade n se ojo ibi,api baide tuuuu yuuu dadi ati dota,emi yin a sopo odun laye,e o ni i ku fota yo lase Olorun
Saturday, April 6, 2024
Api baide tuuu yuuuu Sheikh Akewusola
Gbogbo ojo kefa osu kerin in ni ayajo ojo ibi Sheikh Ajibade Iyanda Abdul Ganiy Adekunle Akewusola Olohun nidahun adura,oludasile ijo istijabah D'uah kaakiri agbaye ati alase ileese Asofam kaakiri orile ede yii,ohun to tun je ki ayeye ojo ibi alaanu awon mekunnu yii yato ni pe,ojo kanna an loun ati akobi re Alaaja Sofiat Ajibade n se ojo ibi,api baide tuuuu yuuu dadi ati dota,emi yin a sopo odun laye,e o ni i ku fota yo lase Olorun
Ẹka Iroyin
# Lagbo Amuludun
Pin-in Kaakiri
NIPA IROYIN TOJUBOLE
Lagbo Amuludun
Labels:
Lagbo Amuludun
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
Author Details
Iroyin Tojubọle jẹ iroyin ori ayelujara to n kọ nipa awọn ohun to n lọ lagbegbe wa, yala l'agbo amuludun, iyẹn awọn oṣere; iṣẹlẹ kayeefi; eto oṣelu ati iṣejọba pẹlu oniruuru ẹka iroyin kaakiri agbaye.

No comments:
Post a Comment