Showing posts with label Esin. Show all posts
Showing posts with label Esin. Show all posts
Thursday, November 14, 2024
Friday, September 27, 2024
Furaide oni ni o,aṣalẹ Luli tijọ Genesis Global gbe kalẹ
IROYIN TOJUBOLE
September 27, 2024
0
Agbọlade Oluwatoyin Furaide oni ọjọ kẹtadinlọgbọn oṣu kẹsan yii gan an niṣọ oru agbayanu naa maa waye ninu ijọ Genesis Global to wa nilu Ala...
Kaa Siwaju »
Furaide oni ni o,asale Luli
IROYIN TOJUBOLE
September 27, 2024
0
Ijo Genesis Global to wa ni Alakuko ipinle Eko ni asale Luli nibiti ise ami ati iyanu yoo ti waye latowo emimimo nipase Oluso Oladele Ogundi...
Kaa Siwaju »
Thursday, September 26, 2024
Ilu Abeokuta yoo gbalejo emimimo lati inu ijo Genesis Global
IROYIN TOJUBOLE
September 26, 2024
0
Ọba Adelẹyẹ park,Ṣokori ori omi ni isọji agbayanu latinu ijọ Genesis global yoo ti waye,ọjọ kinni si ọjọ kẹta oṣu kẹwa yii ni ọpọ ide yoo ti...
Kaa Siwaju »
Ijọ Genesis Global n gbe isọji alagbara bọ silu Abẹokuta
IROYIN TOJUBOLE
September 26, 2024
0
Ọjọ kinni si ọjọ kẹta oṣu kẹwa ni ijọ Genesis Global yoo sọ isọji alagbara kalẹ si ilu Abẹokuta ipinlẹ Ogun fun igba akọkọ Oludasile ijọ naa...
Kaa Siwaju »
Monday, September 23, 2024
Monday, September 16, 2024
Ileeṣẹ ADRONS n ki awon musulumi ku ayeye odun oni
IROYIN TOJUBOLE
September 16, 2024
0
Ileeṣe ADRONS iyẹn ileeṣẹ to ṣe e fọkan tan ninu ilẹ ati ile tita ti n ki awọn onibara wọn to jẹ musulumi ku ayẹyẹ ọdun Eid Maulud Nabiyy to...
Kaa Siwaju »
Tuesday, August 27, 2024
Oloye Muraina Olanshile,alase ileese Shile Alexandra di Agbaakin Bashorun ile Yoruba
IROYIN TOJUBOLE
August 27, 2024
0
Oonirisa alayeluwa oba Enitan Ogunwusi lo so pe,ipo naa to si ogbontarigi onisowo ile lati ipinle Ogun naa,ojo marun un gbako ni ayeye yii y...
Kaa Siwaju »
Sunday, June 16, 2024
Aare Emmanuelking bawon musulumi sajoyo odun ileyaOluda
IROYIN TOJUBOLE
June 16, 2024
0
Oludasile ileese ADRONS,Aare Emmanuelking ti ba awon musulumi kaakiri agbaye dupe lowo Olorun fun ti ayeye odun ileya odun yii to soju won b...
Kaa Siwaju »
Wednesday, June 5, 2024
Wednesday, May 1, 2024
Saturday, April 27, 2024
Thursday, April 18, 2024
Wednesday, April 10, 2024
Oludasile ileese Adrons,otun asiwaju onigbagbo fun Remo ipinle Ogun n ki awon musulumi ku odun o
IROYIN TOJUBOLE
April 10, 2024
0
Aare Emmanuelking ,oludasile ileese ADRONS iyen ileese to se e fokantan ninu lle ati ilẹ tita ati rira ti n ki awon musulumi ku oriire odun ...
Kaa Siwaju »
Wednesday, April 3, 2024
Oriire nla!!Aarẹ Adetọla ati Yeye Aderonkẹ joye ninu ẹgbẹ CAN nipinlẹ Ogun
IROYIN TOJUBOLE
April 03, 2024
0
Lati fi samin ayẹyẹ ọjọ ibi oludasilẹ ileeṣẹ ADRONS iyẹn Aarẹ Adetọla lo mu ẹgbẹ ajumọṣe onigbagbọ iyẹn CAN nipinle Ogun fi Aare Adetola ati...
Kaa Siwaju »
Tuesday, April 2, 2024
Ileeṣẹ ADRONS lo n ki yin ku ọdun ajinde o
IROYIN TOJUBOLE
April 02, 2024
0
ileeṣẹ ADRONS kaakiri agbaye ti n fi asiko yii ki awọn onibara wọn kaakiri agbaye ku ọdun ajinde paapaa awọn ọmọlẹyin Jesu Kristi Olugbala ,...
Kaa Siwaju »
Saturday, March 30, 2024
Sannde ọla ni iṣo oru alagbara ti ijọ Genesis Global yoo waye nilu EkoỌla
IROYIN TOJUBOLE
March 30, 2024
0
Sannde ọla yii gan an ni aṣalẹ isọji alagbara ti ijọ Genesis global ṣagbekalẹ rẹ yoo waye ni olu ijọ wọn to wa ni,Duro Iṣọla ni Alakukọ nipi...
Kaa Siwaju »
Saturday, March 23, 2024
Ijọ istijabah D'uah ṣe waasi Ramadan nilu Idiroko
IROYIN TOJUBOLE
March 23, 2024
0
Ẹsẹ o gbero lọjọ satide ọjọ kẹtalelogun oṣu yii nigbati ijọ istijabah ṣe waasi ramadan ẹlẹẹkẹsan iru ẹ nilu Idiroko nipinlẹ Ogun,Sheik Ajiba...
Kaa Siwaju »
Sunday, March 17, 2024
Author Details
Iroyin Tojubọle jẹ iroyin ori ayelujara to n kọ nipa awọn ohun to n lọ lagbegbe wa, yala l'agbo amuludun, iyẹn awọn oṣere; iṣẹlẹ kayeefi; eto oṣelu ati iṣejọba pẹlu oniruuru ẹka iroyin kaakiri agbaye.
Ikanni Ayelujara