Ijọ istijabah D'uah ṣe waasi Ramadan nilu Idiroko - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Saturday, March 23, 2024

Ijọ istijabah D'uah ṣe waasi Ramadan nilu Idiroko


Ẹsẹ o gbero lọjọ satide ọjọ kẹtalelogun oṣu yii nigbati ijọ istijabah ṣe waasi ramadan ẹlẹẹkẹsan iru ẹ nilu Idiroko nipinlẹ Ogun,Sheik Ajibade Akewuṣọla ni olugbalejo agba, nigbati Sheik Kabiti Apọnle Anọbi ṣe waasi lọjọ naa awọn ọba alade bii onipokia ti ipokia ọba Yisau Oluṣọla wa nibẹ lọjọ naa

No comments:

Post a Comment

Pages