O mase o,Rachel Oniga oseretiata ti ku o - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo


Workers delight

Saturday, July 31, 2021

O mase o,Rachel Oniga oseretiata ti ku o

Iroyin to te tojubole lowo so pe gbajumo oseretiata naa ku lana furaide ni eni odun merinlelogota,Rachel to ti kopa ninu opolopo sinima agbelewo ti ta teru nipa,ohun to sokunfa iku e ni enikeni ko le so nitori oloogbe si wa ni oko ere kan nilu Mowe lose yii.


No comments:

Post a Comment

Pages