
Ojo jimo to koja lo yii ni iroyin naa gba igboro pe okan ninu awon ibeji Ajogbajesu ku,Jide Taiwo Ajogbajesu lo je ipe Olorun leyin aisan ojo pipe,awon ibeji yii to ti bere ise Orin kristeni lati bii Ogun odun seyin la gbo pe won ki n se ibeji sugbon ti won je ore timotimo Koda soosi iya oloogbe ni won ti pade ti Oro won si wo,won bere si i ni korin papo labe ileese Bayowa to je ti Ogbeni Gbenga Adewusi.


No comments:
Post a Comment