Oloye Rafiu Okanlawon Oseni sepade pelu awon olugbe agbegbe re lori iwode ati ifehonuhan ose yii - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Tuesday, July 30, 2024

Oloye Rafiu Okanlawon Oseni sepade pelu awon olugbe agbegbe re lori iwode ati ifehonuhan ose yii


Odu ni Oloye Rafiu Okanlawon Oseni eniti opo eeyan mo si Elele je,apagunpote ilu Igbein ki n se aimo fun gbogbo olugbe ipinle re,Oloye to gbajumo yii ti wa sepade pelu awon olugbe agbegbe Mowe,Ofada ati awon ilu mi in to yi won ka loni ojo tuside to si ti je ko di mimo pe,ki won se jeje lasiko iwode ati ifehonuhan ti yoo waye lose yii
Oloye Elele ninu oro re lo ti so pe,Aare Bola Tinubu ni erongba rere lokan fun gbogbo olugbe ati omo bibi Orile ede yii sugbon omi lo si po ju oka lo fun Aare wa.
Apagunpote ilu Igbein ni Abeokuta ipinle Ogun ti wa so pe,kawon eeyan oun mase lowo ninu ija lasiko iwode ki alaafia le joba,o wa be olori fawon Hausa agbegbe re pe,ife nikan lo le mu ilu tesiwaju .

No comments:

Post a Comment

Pages