Odu ni ileeṣẹ ADRONS jẹ laarin awọn ileeṣẹ to n ta ilè ati ilẹ,gege bi onibara won fun igba akoko awon ohun to ye ki o mo nipa won re e ati idi to se ye ki o ba won dowo po,idi mewa ti ileese ADRONS ṣe jẹ aṣiwaju re e:
**Ileese ADRONS n tọ awọn onibara won sona pelu igboya pe,won le di onile lori laarin asiko perente.
**Ileese ADRONS ni awon agbejoro to le ba e se awon iwe ile latodo ijoba bii C of O lona irorun pelu ifokanbale pe,o ti di onile lori
**Ileese yii n gba sisan owo diedie lati le mu ko rorun fawon onibara lati tete di onile lori.
**ADRONS yoo beere ohun ti o fe fi ile ti o fe ra se boya,ohun osin,ise agbe,ile gbigbe lati le mo adugbo ati ipinle ti irufe ile ti o fe wa,won ni ile kaakiri orile ede yii bii ipinle Ogun,Oyo,Eko,Nassarawa,Ekiti ,Niger.
**ADRONS yoo mu e lo ye ile ti o fe ra wo pelu yin lati nawo si iru ile ti e fe.
**Ileese yii yoo gba yin nimoran lori ileese ti e le ko sawon adugbo ti e ba ra ile si lodo won,iyen to ba je pe ileese le fe fi ile naa ko.
**ADRONS ti pe odun mejila nidi ise ile tita,o gba pe ,oruko rere san ju wura lo,idi eyi ni won se n se ooto.
***ADRONS mo pe,ile n gbowo lori lojoojumo,ere pupo lo wa lori ile ti e ba ra lodo won iyen boya e o fe ko ohunkohun sori ile naa lasiko ti e ra a.
**O ni awon ohun amayederu bii ina ijoba,ona to ja geere,ile iwosan igbalode,ile itaja ati ibi igbafe lo wa lawon esiteeti ADRONS.
**Wọn mọ riri onibara wọn,ajọṣepọ to danmọran maa n tesiwaju laarin won koda leyin opo odun ti e ti ra ile lodo won.
Boya iwo fe ra ile nileese Adrons,o le pe nomba yii 08138432335 tabi ki o lo si eyikeyi ileese won to wa nitosi e
No comments:
Post a Comment