Showing posts with label Ile-Ejo. Show all posts
Showing posts with label Ile-Ejo. Show all posts
Saturday, October 26, 2024
Thursday, October 24, 2024
Saturday, October 12, 2024
Owo ti te onisowo oko ayokele ,owo adigunjale lo ti ma n ra oko to n ta
IROYIN TOJUBOLE
October 12, 2024
0
Toyin Agbolade Samuel Durojaye loruko okunrin naa ,Falomo ni Eko lo ti n ta oko ayokele ti asiri si ti pada tu pe,owo David Kesh to je mekan...
Kaa Siwaju »
Friday, October 11, 2024
Sunday, September 15, 2024
Friday, September 13, 2024
Monday, September 9, 2024
Saturday, August 10, 2024
Sunday, July 7, 2024
Saturday, June 29, 2024
Ẹjọ ṣi wa nile ẹjọ o,ki oloye Allinson Ọladimeji maṣe pe ara ẹ ni Alagura tilu Agura Ṣagamu lasiko yii rara
IROYIN TOJUBOLE
June 29, 2024
0
Adajọ agba tile ẹjọ giga to wa ni Ṣagamu nipinlẹ Ogun ,adajọ Tajudeen Okunṣọkan ti sọ pe ,ki Oloye Ọladimeji Allinson maṣe pe ara ẹ ni Alagu...
Kaa Siwaju »
Saturday, June 15, 2024
Thursday, May 23, 2024
Saturday, May 11, 2024
Ọwọ ti tẹ Abikẹ o,awọn ọmọleewe girama lo n fi ṣiṣẹ aṣẹwo ni orilẹede Libya
IROYIN TOJUBOLE
May 11, 2024
0
Awọn ọmọleewe Adeoye Lambo ni Ọbada Oko nitosi Abẹokuta nipinlẹ Ogun ni arabinrin to n jẹ Abikẹ Ọlọnade maa n ko lọ si orilẹede Libya lati l...
Kaa Siwaju »
Saturday, March 23, 2024
Monday, February 19, 2024
Ẹgbẹ apoogun ti f'ẹsun ibanilorukọ jẹ kan Abati,Chukwunedu ,bẹẹni ileeṣẹ BULLION GO-NEAT n beere fun idajọ ododo
IROYIN TOJUBOLE
February 19, 2024
0
Ileeṣẹ BULLION-GO-NEAT iyẹn ileeṣẹ to n ṣe oogun amara ji pepe to n jẹ COCO SAMBA, ti sọ pe ,irọ nla ni iroyin to n lọ nigboro pe oogun olom...
Kaa Siwaju »
Friday, February 9, 2024
E wa gbo idajo ti won fun awon to fesun ole jija kan Lizzy Anjorin oseretiata yoruba
IROYIN TOJUBOLE
February 09, 2024
0
Adajo nile ejo giga kan nipinle Eko ti so pe kawon mefa te n wo aworan won yii lo wa tuu onduredi taosan lati fi gba beeli ara won pelu onid...
Kaa Siwaju »
Tuesday, June 27, 2023
O Mase o,ogba ewon ni Trinity guy yoo ti sodun ileya
IROYIN TOJUBOLE
June 27, 2023
0
Esun pe,o n Fi Oro ibalopo lo Omo kekere Koda a gbo pe awon obi Omo yii naa wa nibe lojo naa ,idi eyi ni adajo se pase pe ki Trinity guy ata...
Kaa Siwaju »
Wednesday, March 15, 2023
Owo te awon adigunjale ti won n yo awon ara Ewekoro lenuo
IROYIN TOJUBOLE
March 15, 2023
0
Owo iko Olopaa ipinle Ogun ti te awon adigunjale meta toruko won n je, Ahmed,Sunday ati Jimoh lenu lagbegbe Ewekoro nipinle Ogun,ti Inu awon...
Kaa Siwaju »
Ifeoma pa lanloodu re ni Sango Ota
IROYIN TOJUBOLE
March 15, 2023
0
Ifeoma Ossai loruko obinrin te n wo aworan e yii,o ti pa lanloodu e nilu Sango Ota nipinle Ogun lojo Monde ose yii,oloogbe Oladele Surulere ...
Kaa Siwaju »
Author Details
Iroyin Tojubọle jẹ iroyin ori ayelujara to n kọ nipa awọn ohun to n lọ lagbegbe wa, yala l'agbo amuludun, iyẹn awọn oṣere; iṣẹlẹ kayeefi; eto oṣelu ati iṣejọba pẹlu oniruuru ẹka iroyin kaakiri agbaye.
Ikanni Ayelujara