Ọwọ ti tẹ Abikẹ o,awọn ọmọleewe girama lo n fi ṣiṣẹ aṣẹwo ni orilẹede Libya - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Saturday, May 11, 2024

Ọwọ ti tẹ Abikẹ o,awọn ọmọleewe girama lo n fi ṣiṣẹ aṣẹwo ni orilẹede Libya


Awọn ọmọleewe Adeoye Lambo ni Ọbada Oko nitosi Abẹokuta nipinlẹ Ogun ni arabinrin to n jẹ Abikẹ Ọlọnade maa n ko lọ si orilẹede Libya lati lọ fi ṣiṣẹ nọọbi ṣugbọn ti ọwọ ikọ ọlọpaa ipinlẹ Ogun ti tẹ ẹ ,agbenusọ ọlọpaa ipinlẹ Ogun,Ọmọlọla Odutọla fidi ẹ mulẹ to si sọ pe yoo foju bale ẹjọ laipẹ

No comments:

Post a Comment

Pages