Aṣiri tu!Johnson Ajibọla Akindele n wa iṣubu Ọnọrebu Adekunle Lateef o - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Tuesday, December 23, 2025

Aṣiri tu!Johnson Ajibọla Akindele n wa iṣubu Ọnọrebu Adekunle Lateef o

Ọjọ gbogbo ni tole,ọjọ kan ni ti olohun,owe yii gan an lo ṣẹ mọ Alagba kan torukọ ẹ n jẹ,Johnson Ajibola Akindele lara laipe yii pelu bo se n gbero lati gbe wahala sinu aye gbajumo oloselu nijoba ibile Owode Egba iyen Onorebu Adekunle Lateef.
Ninu fonran kan to jade laipe yii la ti gbo lasiko ti Johnson n soro Onorebu yii fun enikan lori foonu pe,awon maa sise yen pa ninu aye Onorebu Adekunle to tun je onisowo ile ati ilẹ tita lagbegbe naa.
Johnson so pe,ibi poultry tawon yonda fun Onorebu lati ta tele lawon tun maa pada lo sise nitori awon fe ko maa ba wahala to wa ladugbo naa fa a nitori lara wahala to ba ko si lawon ti maa rowo beeni oun setan lati sise yen pa kawon le ri owo ati pe,oun fe ko ri wahala lasiko odun keresimesi ati odun tuntun 
Sa o,opo awon to gbo ohun ti Johnson so yii ni won ti n so pe,ika ni bee lo je onilara eda ti ko gbero ohun rere ro Kanselo woodu Owode Egba rara.

No comments:

Post a Comment

Pages