Adajo nile ejo giga kan nipinle Eko ti so pe kawon mefa te n wo aworan won yii lo wa tuu onduredi taosan lati fi gba beeli ara won pelu oniduro to dangajia to je olugbe ipinle EKo
Ojo monde to koja lawon eeyan yii fesun ole jija kan arewa oseretiata yoruba toruko re n je Lizzy Anjorin ninu oja kan to gbajumo nilu Eko
Ni bayii ti ile ejo ti pase pe awon eeyan yii jebi fifi esun ole jija kan eeyan laisi eri to daju ti eyi si lodi si ofin orile ede Naijiria,sugbon ti won ko ba ri eni duro tabi sanwo beeli won,ogba ewon ni won yoo wa di osu to n bo.

No comments:
Post a Comment