Kayeefi niku Alaaji Ayuba Abdullai to je osisee ni yunifasiti Kwara je lojo ti orile ede Naijiria figagbaja pelu iko BafanaBafana ninu idije ere boolu to n lo lowo lorile ede Cote D'ivore nibiti orile ede yii ti jawe olubori,a gbo pe ifunpa oloogbe deede ga lojiji sugbon ti elemi pada gba a ki won to gbe e de ile iwosan
Ninu iroyin miiran la tun ti gbo pe,agunbaniro toruko re n je Samuel naa subu nipinle Adamawa lasiko ti orileede yii n gba penariti ,ijaya lo mu oun naa mudi lo sile to si je ipe Olorun.A gbo pe baba olowo kan lati ipinle Anambra to fi orile ede ivory coast sebugbe ,oloye Osondu naa ku lojo ti a n so yii ti a si gbo pe ifunpa giga lo pa oun naa

No comments:
Post a Comment