Owo te awon adigunjale ti won n yo awon ara Ewekoro lenuo - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Wednesday, March 15, 2023

Owo te awon adigunjale ti won n yo awon ara Ewekoro lenuo


Owo iko Olopaa ipinle Ogun ti te awon adigunjale meta toruko won n je, Ahmed,Sunday ati Jimoh lenu lagbegbe Ewekoro nipinle Ogun,ti Inu awon olugbe agbegbe naa si ti n dun bayii
Awon adigunjale yii ti wa ni olu ileese Olopaa to wa ni ipinle Ogun iyen Eleweeran bayii

No comments:

Post a Comment

Pages