Ẹjọ ṣi wa nile ẹjọ o,ki oloye Allinson Ọladimeji maṣe pe ara ẹ ni Alagura tilu Agura Ṣagamu lasiko yii rara - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Saturday, June 29, 2024

Ẹjọ ṣi wa nile ẹjọ o,ki oloye Allinson Ọladimeji maṣe pe ara ẹ ni Alagura tilu Agura Ṣagamu lasiko yii rara

Adajọ agba tile ẹjọ giga to wa ni Ṣagamu nipinlẹ Ogun ,adajọ Tajudeen Okunṣọkan ti sọ pe ,ki Oloye Ọladimeji Allinson maṣe pe ara ẹ ni Alagura tilu Agura nitosi Sabo Ṣagamu mọ titi ti ile ẹjọ yoo fi dajọ naa
O sọ pe oloye Allinson ki n ṣe mọlẹbi Olubọdun rara bẹẹ lo dẹ jẹ pe idile Olubọdun nipo ọba kan lẹyin ipapoda ọba ana,ọba Adeyẹmi Lawal
Idile Olubọdun ti wa n bẹ awọn olugbe agbegbe naa lati maṣe ba oloye Allinson dowopọ titi ti ile ẹjọ yoo fi ṣedajọ.

No comments:

Post a Comment

Pages