Toyin Agbolade
Samuel Durojaye loruko okunrin naa ,Falomo ni Eko lo ti n ta oko ayokele ti asiri si ti pada tu pe,owo David Kesh to je mekaniiki lo ti n ra oko to n ta yii ti yoo si tun oda ara awon oko naa kun fun tita.
David to je mekaniiki ma n ji oko awon onibara e ra ni yoo si ta a lowo pooku fun Samuel,sugbon ti owo ti pada te won bayii
No comments:
Post a Comment