Toyin Agbolade
Adugbo Cement nitosi Dopemu nipinle Eko nisele kayeefi naa ti sele lojo satide to koja,lasiko ti oko akero kan lo kolu katapila to duro jeje ara e segbe titi ijoba.
Ogbeni kan to n ti wiibairo lo lasiko naa ni oko akero yii run mo egbe katapila naa to si je ipe Olorun lesekese
Won ti fa oku oloogbe le awon olopaa tesan Afonja lowo ti ajo Lastma si ti gba awon onimoto nimoran lati maa wa oko jeje ,beeni dereba oko akero ti wa lago olopaa lasiko yii
No comments:
Post a Comment