Ifeoma Ossai loruko obinrin te n wo aworan e yii,o ti pa lanloodu e nilu Sango Ota nipinle Ogun lojo Monde ose yii,oloogbe Oladele Surulere eni aadota odun je ipe Olorun nigba ti ifeoma eni odun mejilelogbon woya ijakadi pelu e nitori owo Ina ijoba
A gbo pe'kini'baba lanloodu ni Ifeoma gba mu,to si fi n fa a titi ti o fi subu,ti o si daku sugbon ti elemii ti gba a ki won to gbe e de Ile iwosan ijoba to wa niyesi It's
Dpo tesan Sango iyen Csp Salem Dahiru fidi isele naa mule to si so pe ejo naa ti wa ni olu ileese Olopaa ipinle Ogun Eleweeran bayii

No comments:
Post a Comment