Nitori foto ihoho oju ara re tawon kan fi sita,awon Ololufe Laide Bakare n binu si i - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Wednesday, March 15, 2023

Nitori foto ihoho oju ara re tawon kan fi sita,awon Ololufe Laide Bakare n binu si i


Loooto ni Laide Bakare to je arewa obinrin obinrin ti so pe,iro ni awon to fi foto ihoho oun sita n pa mo oun ati pe ki n se aworan oju ara oun lo wa ninu foto naa sugbon tawon kan ti n so kiri pe, Laide lo wa ninu e,opo awon ololufe e ni won ti soro pe ohun ti eni to fi foto yii sori ero ayelujara se ku die kaa to bee lo ye ki onitohun mo pe Olorun wa
Opo awon ololufe Laide ni won ti n ju bombu Oro si i pe ,oun to ye ko je awokose rere fawon ogo weere Orile ede yii ni won ba ninu iwa buruku paapaa to tun je Alaaja to ti lo si Meka ri sugbon ti Laide ti n so kiri pe,oun ko loun wa ninu foto nibi ti won ti si'oju abe re sita fawon eeyan lati wo.

No comments:

Post a Comment

Pages