Ọjọ kinni si ọjọ kẹta oṣu kẹwa ni ijọ Genesis Global yoo sọ isọji alagbara kalẹ si ilu Abẹokuta ipinlẹ Ogun fun igba akọkọ
Oludasile ijọ naa ,Oluṣọ Isreal Ogundipẹ ti sọ pe,ọpọ iṣẹ ami ati iyanu ni Ọlọrun yoo ṣe nibi isọji ọlọjọ mẹta naa
NIPA IROYIN TOJUBOLE
No comments:
Post a Comment