Ilu Abeokuta yoo gbalejo emimimo lati inu ijo Genesis Global - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Thursday, September 26, 2024

Ilu Abeokuta yoo gbalejo emimimo lati inu ijo Genesis Global


Ọba Adelẹyẹ park,Ṣokori ori omi ni isọji agbayanu latinu ijọ Genesis global yoo ti waye,ọjọ kinni si ọjọ kẹta oṣu kẹwa yii ni ọpọ ide yoo ti tu nibi isọji alakọkọ iru rẹ ti ijọ CCC Genesis Global gbe kale
Fun alaye lekunrere e pe oluso Oladele Isreal to je oludasile ijo sori ,08039403425.Jesu Olugbala n duro de ọ

No comments:

Post a Comment

Pages