Furaide oni ni o,asale Luli - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Friday, September 27, 2024

Furaide oni ni o,asale Luli


Ijo Genesis Global to wa ni Alakuko ipinle Eko ni asale Luli nibiti ise ami ati iyanu yoo ti waye latowo emimimo nipase Oluso Oladele Ogundipe Genesis
Tete wa pade Jesu Olugbala ki itan aye re le yipada si rere



No comments:

Post a Comment

Pages