Agbọlade Oluwatoyin
Furaide oni ọjọ kẹtadinlọgbọn oṣu kẹsan yii gan an niṣọ oru agbayanu naa maa waye ninu ijọ Genesis Global to wa nilu Alakuko ipinle Eko
Oluso Oladele Ogundipe Genesis to je oludasile ijo naa ni emimimo yoo ti owo re sise ami ati iyanu,tete maa gbe isoro re bo lodo Jesu Olugbala
No comments:
Post a Comment