Laipẹ yii ni ileeṣẹ ADRONS iyẹn ileeṣẹ to finilọkan balẹ ninu tita ilẹ lọna irọrun ṣabẹwo si aafin Ọọniriṣa ọba Ẹnitan Ogunwusi Ọjaja keji ,ti ileese ADRONS si tun ṣeleri lati gbaruku ti ọdun ọlọjọ to ma n waye nilu ile ifẹ
Ọdun kẹfa re e ti ileese naa ti n sagbateru odun nla to ma n waye ni ile ife yii,lasiko ti asoju oludasile ileese naa n soro laafin Oonirisha ni,arabinrin Adenike Ajobo ti so pe,ohun iwuri ni bi odun olojo yii se ma n mu opo awon omo bibi ile ife loke okun wa sile beeni odun yii ko le je ki asa yoruba pare
Arabinrin Adenike to soju Aare Emanuelking iyen oga agba ati oludasile ileese ADRONS ti wa sọ pe,ifẹ ti gbogbo ọmọ ilẹ kaarọ o jiire nlo nikan lo le mu ilọsiwaju ba iran yoruba kaakiri agbaye.
Ọjọ kọkandinlọgbọn ni ileeṣẹ yii ṣabẹwo si aafin Ọọniriṣa ti akọkọ ọba nilẹ yoruba si tẹwọ gba wọn pẹlu ifẹ.
Boya iwọ fẹ ba ileeṣẹ ADRONS dowopọ ,tete lọ si ọfiisi wọn to ba wa nitosi ọdọ ẹ nitori ileeṣẹ ADRONS ti di araba laarin awọn akẹgbẹẹ ẹ
No comments:
Post a Comment