Lati fi samin ayẹyẹ ọjọ ibi oludasilẹ ileeṣẹ ADRONS iyẹn Aarẹ Adetọla lo mu ẹgbẹ ajumọṣe onigbagbọ iyẹn CAN nipinle Ogun fi Aare Adetola ati iyawo e Yeye Aderonke Adetola joye Otun asiwaju ati yeye Otun asiwaju onigbagbo fegbe CAN nipinle naa lojo keta osu yii labe isakoso Bisoobu Tunde Akin Akinsanya ,ayeye naa waye ninu ijo Communion Faith Assembly Garden of faith ,Kemta Idi Aba Abeokuta.
Opo awon ololufe Aare Adetola ni won ba a sajoyo toun naa si dupe lowo ebi,ore ati egbe onigbagbo lapapo

No comments:
Post a Comment