Sannde ọla ni iṣo oru alagbara ti ijọ Genesis Global yoo waye nilu EkoỌla - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Saturday, March 30, 2024

Sannde ọla ni iṣo oru alagbara ti ijọ Genesis Global yoo waye nilu EkoỌla


Sannde ọla yii gan an ni aṣalẹ isọji alagbara ti ijọ Genesis global ṣagbekalẹ rẹ yoo waye ni olu ijọ wọn to wa ni,Duro Iṣọla ni Alakukọ nipinlẹ Eko nibiti Oluṣọ Ọladele Isreal Ogundipẹ atawọn iranṣẹ Ọlọrun miran yoo ti fi adura ati agbara to wa ninu ajinde ati iku Jesu tu ide ọpọ eeyan,oru sannde mọju monde ni iṣọ oru yii yoo waye o.Ma a bọ Jesu olugbala n duro de ọ

No comments:

Post a Comment

Pages