Egbe sorosoro ipinle Eko se waasi Awe Ramadan - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Friday, March 29, 2024

Egbe sorosoro ipinle Eko se waasi Awe Ramadan


Inu ogba redio AIT ni Alagbado nipinle Eko kun bamubamu lojo toside ose yii lasiko ti egbe sorosoro eka ti ipinle Eko se waasi awe Ramadan odun yii awon agba oje nidi ise sorosoro bii,Kabiesi Owurolawa,Aare Afefe oro,Baba Gboin,dokita Olutayo Somide,Labake Olojede,Alaaji Bamtale,Alaaji Wale Omotola,Dugbe,Yemi Ajide,Afadapakuro,Alaaji Enudunjuyo,Alaaja Erinoso,Tosyno Oloriire,Laafin Ara,iya photo,olori Adeola Balogun atopo sorosoro lo wa nibe,Ere Asalatu ati Alaaji Akasho pelu Alaaja Sukura Akobi Ayeloyun lo fi orin isilaamu da awon eeyan laraya lojo naa

No comments:

Post a Comment

Pages