Api baide tuu yuuuu,Aarẹ Emmanuelking - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Tuesday, April 2, 2024

Api baide tuu yuuuu,Aarẹ Emmanuelking


Gbogbo ojo keji osu kerin in ni ayajo ojo ibi oludasile ileese ADRONS iyen ileese to se e fokantan ninu ile ati ilẹ tita,Aarẹ Emmanuelking ogbontarigi onisowo ile to tun je Aarẹ Apesinọla fun ilẹ Ibadan nipinlẹ Ọyọ lo n ṣọjọ ibi loni in,ma jo sibi to wun ẹ jare,ọrẹ mẹkunnu oloore awọn oniroyin jakejado orilẹ ede Naijiria,ọmọ Ijẹbu Alaare,adura ti wa ni pe,ẹmi ẹ a ṣọpọ ọdun laye ninu alaafia,owo ati ilera pipe,api baide tu yuuuu sa.

No comments:

Post a Comment

Pages