Ileeṣẹ ADRONS lo n ki yin ku ọdun ajinde o - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Tuesday, April 2, 2024

Ileeṣẹ ADRONS lo n ki yin ku ọdun ajinde o


ileeṣẹ ADRONS kaakiri agbaye ti n fi asiko yii ki awọn onibara wọn kaakiri agbaye ku ọdun ajinde paapaa awọn ọmọlẹyin Jesu Kristi Olugbala ,bẹẹni oludasilẹ ileeṣẹ naa Oloye Emmanuelking ti n so pe ,o dara kawon onigbagbo fifehan si ara won nipa fifun awon alaini lebun ati sise itore anu
O salaye pe Jesu ku nitori awa eeyan ni ,ko si ife to tun le to eyi ti Jesu ti fi han si wa,o Aare Apesinola ilu Ibadan ti wa so pe,ife lakoja ofin o dara ka fi ife ba ara wa lo gege bii musulumi ati onigbagbo lasiko odun ajinde yii ati leyin re pelu
Boya eyin si fe ba ileese Adrons dowopo nipa rira ile ati ilẹ,e kan si wọn ni eyikeyi ọfiisi wọn to ba sunmọ yin.

No comments:

Post a Comment

Pages