Ileeṣe ADRONS iyẹn ileeṣẹ to ṣe e fọkan tan ninu ilẹ ati ile tita ti n ki awọn onibara wọn to jẹ musulumi ku ayẹyẹ ọdun Eid Maulud Nabiyy to waye loni.
Bẹẹni wọn n dupẹ lọwọ wọn fun ifẹ aiṣẹtan ti wọn ni si wọn,lasiko ti oludasilè ileeṣẹ ADRONS,Aarẹ Emmanuelking n soro lo ti so pe,ife lo ye kawon musulumi ni si ara won ,ki won maa fife han nitori ife ni Ọlọrun.
O sọ pe,ki wọn mọ pe ọkanṣoṣo ni Ọlọrun ati pe pẹlu ifẹ aiṣẹtan Orilẹ ede wa yoo tẹsiwaju ,ohun gbogbo yoo si pada sipo laipẹ.
Ẹ ma gbagbe pe,ilẹ ṣi wa fun tita nileeṣẹ ADRONS kaakiri origun mẹrẹẹrin orilẹ ede yii,o le kan si eyikeyi ọfiisi wọn to ba wa nitosi ẹ.ADRONS araba ni baba lọjọkọjọ.
No comments:
Post a Comment