Oludasile ileese Adrons,otun asiwaju onigbagbo fun Remo ipinle Ogun n ki awon musulumi ku odun o - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Wednesday, April 10, 2024

Oludasile ileese Adrons,otun asiwaju onigbagbo fun Remo ipinle Ogun n ki awon musulumi ku odun o


Aare Emmanuelking ,oludasile ileese ADRONS iyen ileese to se e fokantan ninu lle ati ilẹ tita ati rira ti n ki awon musulumi ku oriire odun itunu awe todun yii bee lo n be won lati fi ife lo ki won si tesiwaju ninu ise rere ati iwa rere ti won n wu lasiko aawe,Aare Apesinola ilu Ibadan ti wa so pe ife lakoja ofin inu Olorun si maa n du si awon to n fife ba ara won se.

No comments:

Post a Comment

Pages