Ayoka Ọlọgẹdẹ agba ọjẹ oṣeretiata obinrin lo n ṣọjọ ibi loni in - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Monday, April 8, 2024

Ayoka Ọlọgẹdẹ agba ọjẹ oṣeretiata obinrin lo n ṣọjọ ibi loni in


Oni yii ni ayajọ ọjọ ibi gbajumọ oṣeretiata nni to tun fẹran lati maa ko ipa ajẹ ninu fiimu agbelewo yoruba, Ayandọtun Ayoka Ologede,api baide tuuu yuuuu mama daadaa,emi e a sopo odun laye eeyan iyi.

No comments:

Post a Comment

Pages