Elemi okunkun ni Ooni, Elemi kukuru ni Naomi--Woli Faleyinmu - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Wednesday, November 16, 2022

Elemi okunkun ni Ooni, Elemi kukuru ni Naomi--Woli Faleyinmu

Ose yii ni tojubole sabewo si Ile Wolii Faleyinmu to je ariran agbaye,Wolii yii lo so nigba kan pe,Buhari yoo di Aare ati pe oun ko ni mesaya wa rara,bee lo so nigba naa pe Oloogbe M.k.o Abiola ko le di Olori Orile ede yii.
Ni bayii Wolii Faleyinmu ti so pe kawon molebi Ooni Ile Ife iyen oba Adeyeye Ogunwusi lo kun fun adura nitori awon obinrin pupa to fe yen le maje ko pe laye rara nitori won ko ba eleda re mu ati pe aborisa ati Elemi okunkun ni.
Woli to ti so asotele ri nipa Olori Naomi pe ,odun merin pere ni yoo lo laafin Ooni nitori oonirisa ko ni alabarin ti a ko mo Naomi latode orun rara beeni baba yii tun ti wa so pe ,Elemi kukuru ni Olori ana loose Onirisa.Ati pe kawon molebi re gbadura fun un beeni ki won mojuto Tadenikawo iyen omo ti Olori Naomi bi fun Ooni Ile Ife nitori Wolii nla lomo naa lojo iwaju.


No comments:

Post a Comment

Pages