
Inu Gbongan nla kan nitosi Ikeja nipinle Eko ni ayeye igbeyawo bonkele ti iyawo Oloogbe Alaaji Fatai Oko Oloyun se ti waye,a gbo pe Sir Shina Peter's lo dalubole, sugbon awon kan ti n gbe e kiri pe Loya oloogbe Alaaji Oko Oloyun ni iyawo re segbeyawo pelu ti iwa yii ko si dunmo awon omo mefa ti obinrin naa bi fun Oloogbe Oko Oloyun ninu.


No comments:
Post a Comment