Odu ni Afefe Oro je lawujo awon sorosoro sugbon nitori Ife to ni si asa ati ise Ile wa lo mu u darapo mo awon egbe oseretiata to si n se daadaa.
Aimoye opo iwe akonilogbon bii Orere Aye atawon mi in lo ti ko,bee lo ti se sinima orisirisi sugbon to je pe asiri ikooko lo n ta warawara lori ero ayelujara YouTube bayii.


No comments:
Post a Comment