Lekan Ojo Gbatami jade laye,Omi lo di si igbaaya e - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Thursday, November 17, 2022

Lekan Ojo Gbatami jade laye,Omi lo di si igbaaya e

Odu mi Oloogbe Lekan Ojo Gbatami je,opo fiimu olopolo pipe ni omo Bibi ilu Ijesha yii ti se sugbon o seni laamu pe iku ti yo owo e lawo.
Gege bi a se gbo pe,Omi di si igbaaya e to si ti lo sise abe loke okun sugbon ti elemii ti pada gba a lojo toside yii.
Olorun yoo duro ti ohun gbogbo ti Gbatami fi sile saye.


No comments:

Post a Comment

Pages