Leyin ti iyawo Arabambi iyen Olori fawon onifuji Wasiu Ayinde joye Seriki iyaloja gbogbo Ile Egba lose to koja ni Emmanuella Ajike okin joye yii,ni oko re Alaaji Wasiu Ayinde tun ra oruka dayamondi fun un.
Ti omo Bibi ilu Abeokuta naa si n dupe lowo omo Ojusagbola fun Ife to fi han si i latigba toun ti fe e gege bii Ade Ori.

No comments:
Post a Comment