Tosin Eniba fe ko awo Orin jade - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Monday, November 21, 2022

Tosin Eniba fe ko awo Orin jade

Gbogbo awon Ololufe yeye Tosin Eniba lo ti setan lati ba obinrin naa sakojade awo Orin re tuntun ti yoo ko jade bi omo tuntun lojo kejilelogun osu kejila odun yii nile itura Nirvana to wa ni agbegbe Ogijo nipinle Ogun.
Aso Ankara ati gele 10,000 fawon obinrin,aso ati fila 7k fawon okunrin ni a o fi wole sibi ayeye lojo naa,Alaaji Sule Also Malaika ati 'Etu Fuji iyen Alaaji Atawewe ni won yoo fi Orin da awon eeyan laraya lojo naa.


No comments:

Post a Comment

Pages