Olorin emi'welu welu'Sammie Okposo ku lojiji - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Friday, November 25, 2022

Olorin emi'welu welu'Sammie Okposo ku lojiji

Ojo furaide yii ni okunrin olorin emi nni iyen Sammie Okposo ku lojiji la i se aisan rara.Eni odun mokanlelaadota ni,a gbo pe o subu ninu Ile re to si gba ibe soda sorun alakeji.Awon kan so pe ironu wa ninu ohun to pay Ogbeni yii pelu awon ohun to koju nipa igbeyawo re lodun to koja.


No comments:

Post a Comment

Pages