Asiri ti pada tu sita pe Saoty Arewa iyen Ojulowo omo gege bii inagije re ti segbeyawo pelu obinrin miiran leyin ti okan ninu iyawo re pariwo sita losu die seyin pe o n ba omo egbon e lo po.
Gele mawobe ni omo Bibi ilu Epe nni we si gbogbo awuyewuye naa nigba yen .Ni bayii Saoty Arewa tun sese segbeyawo pelu Yesira adura wa ni pe eyin iyawo ko ni i mo eni o.
Iroyin Tojubọle jẹ iroyin ori ayelujara to n kọ nipa awọn ohun to n lọ lagbegbe wa, yala l'agbo amuludun, iyẹn awọn oṣere; iṣẹlẹ kayeefi; eto oṣelu ati iṣejọba pẹlu oniruuru ẹka iroyin kaakiri agbaye.
No comments:
Post a Comment