Baba Wura iyen baba iyawo Oko Oloyun ti so pe kawon eeyan tako iroyin eleje tawon obi Oloogbe Alaaji Fatai Oko Oloyun n so kiri pe,iyawo omo won ko toju awon,baba yii so pe iya Ibeji iyen iyawo oko Oloyun n toju awon molebi oko e Koda o sese ra oko ayokele fun meji ninu awon aburo Oko Oloyun ni.
O so pe Wura gan an lo ni Fijk House ati pe oun lo ni owo ti Oloogbe fi bere okoowo oogun to n ta.
O salaye pe iro lawon obi oko Oloyun n pa pe Wura iyen iya Ibeji n fiya je awon nitori baba Oko Oloyun gan an ti n ta Ile ati Ile ti Oko Oloyun fi saye lo

No comments:
Post a Comment