O sele owo ijoba ti te gbajumo oloselu pelu egbogi oloro lowo nipinle Eko - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Thursday, May 13, 2021

O sele owo ijoba ti te gbajumo oloselu pelu egbogi oloro lowo nipinle Eko

Owo ajo to n ri si sise owo ilu mokunmokun ati egbogi oloro ti te igbakeji alaga ijoba ibile Lagos island tele iyen Ogbeni Asekun Kehinde Sakiru pelu egbogi oloro ti owo re din die ni igba milioonu naira.
Papako ofurufu Muritala ni owo ti te Ogbeni yii pelu awon iko re nigba ti won n lo si Orile ede London lojo weside ose yii.Oga agba fun ajo NDLEA Ogbeni Femi Babafemi fidi isele naa mule ti o si so pe ijoba yoo sedajo awon ti owo re naa.


No comments:

Post a Comment

Pages