Olanshile gun oko re pa nitori o fe iyawo le e - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Thursday, May 20, 2021

Olanshile gun oko re pa nitori o fe iyawo le e

Obinrin ti e n wo aworan e yii la gbo pe o ti gun oko re pa nilu ijebu ode,alapata eran ni oko re yii ti o si je pe ise naa ni Lashile n se,oun niyawo kerin loode oko yii,sugbon nigba ti o gbo pe oko oun fe iyawo le oun inu bii agaga nigba to ri iyawo naa ni odo eran,ibinu yii ni Lanshile fi lo ba oko re to si gun un l'ese.
Won gbiyanju lati gbe okunrin naa lo si jenera nilu ijebu ode sugbon ti elemii pada gba a ti won si ti sinku e nilana musulumi,Lanshile ti wa l'ago olopaa ni Eleweran,ti agbenuso olopaa ipinle Ogun Ogbeni Oyeyemi si ti fidi isele naa mule.


No comments:

Post a Comment

Pages