
Ojo tuside ose yii ni gbajumo oseretiata obinrin n ni iyen Aishat Lawal n se ojo ibi e,ti omo Bibi ilu Ibadan naa si n dupe lowo Olorun sugbon ti opo ninu awon ololufe ere fiimu Yoruba ti n so pe aso ti iya olomo kan naa wo ko dara pelu bo se fi gbogbo ara re sile.Sugbon gele mawobe ni Aishat we si gbogbo eebu ti won n bu u.


No comments:
Post a Comment