Owo ajo NDLEA ti te gendekunrin meji,egbogi oloro ni won gbe - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Wednesday, June 2, 2021

Owo ajo NDLEA ti te gendekunrin meji,egbogi oloro ni won gbe

Owo ajo NDLEA ti te gendekunrin meji ni papako ofurufu Ile wa to wa ni olu ilu Abuja pelu egbogi oloro kokeeni.Ogbeni Princewill ati Ogbeni Peter to oun n gbe ni ilu Europe ni owo re,Koda inu ora ounje Golden morn ni won toju egbogi oloro naa si ki owo ajo NDLEA to te won.


No comments:

Post a Comment

Pages