Awon agbalagba okunrin meji yii too sewon dandan ni - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo


Workers delight

Saturday, July 24, 2021

Awon agbalagba okunrin meji yii too sewon dandan ni

Ogbeni Ajewunmi ati Ogbeni Kayode ni adajo Ile ejo kan nipinle Oyo ti so si ewon pelu bi won se fipa ba awon omodebinrin sun, awon baba meji yii ti won ti le ni eni ogota odun ti wa ninu ogba ewon Abolongo nipinle Oyo bayii


No comments:

Post a Comment

Pages