Purofeso Lufadeju to je okan ninu agba egbe Rotary to si tun je oga ni eka eto ifeto somo Bibi ati itoju awon ewe(child health) ti so pe ki awon oniroyin kaakiri Orile ede yii ran awon olugbe Orile ede yii lowo lati mo nipa ifeto somo Bibi.Ijoba apapo ti setan lati je ki awon eeyan mo pe ifeto somo Bibi nikan lo le je ki airi ounje ati aile gbe igbe aye to wun ni di ohun igbagbe.
Toside ojo kinni osu yii ni Minisita fun ilera iyen Dokita Olorunmibe Mamora naa soro nibi eto ifeto somo Bibi ti egbe Rotary Reproductive Martenal and Child Health se,ti o si so pe to ba fi maa di odun 2050 iye awon olugbe Orile ede yii yoo ti po koja siso.ati pe o dara ki gbogbo obinrin mo pe ifeto somo Bibi dara.

No comments:
Post a Comment