Ile ejo ti hi pasito Oni s'ewon gbere nilu Ado Ekiti,ese to se gan an re e - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Friday, July 2, 2021

Ile ejo ti hi pasito Oni s'ewon gbere nilu Ado Ekiti,ese to se gan an re e

Ile ejo giga kan nilu Ado Ekiti ti ju Olori ijo kan to n je Pasito Oni s'ewon gbere pelu esun pe o seku pa obinrin kan to wa aajo omo de odo re.Ile ejo ti wa so pe ki Pasito Oni lo maa gbadun igbesi aye e to ku logba ewon.


No comments:

Post a Comment

Pages