Iyabo Ojo ti toro aforiji lowo egbe Tampan - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Friday, July 2, 2021

Iyabo Ojo ti toro aforiji lowo egbe Tampan

Iyabo Ojo ti so pe ki egbe Tampan labe Aare won iyen Oloye Bolaji Amusan pe ki egbe yii dariji oun ati ikeji oun iyen Nkechi Blessing pe ki awon agbaagba egbe yii fowo wonu,bee lo tun be Omooba Jide Kosoko pe ki baba naa dariji oun ati Nkechi.


No comments:

Post a Comment

Pages