
Oloribfun gbogbo awon onifuji iyen Alaaji Wasiu Ayinde ti dupe lowo Olorun fun ise abe to se lose to koja ti o si saseyori .Ojo satde ose to koja ni omo Ojusagbola gbe e sori ero ayelujara re pe ise abe ti oun se lorile ede yii yori si rere,bee lo tun gbe aworan ounje to je leyin ise abe naa sori ero ayelujara re.Sa o irufe ise abe ti Oluaye se ni enikeni ko le so.


No comments:
Post a Comment