
Oluso ijo Genesis Global iyen Oluso Oladele Ogundipe Genesis ti so pe titejumo ohun ti eda fe da nile aye lo se Pataki,Koda oruko tuntun ti Oluso Oladele n je nigboro bayii ni 'Oluso Focus'ni itumo pe 'tejumo o'koda ijo jijo si Orin naa n dun mo awon omo ijo Genesis kaakiri ti o si je pe Oro isiti to ba orin'focus' ti Oluso Oladele fi se iwaasu naa ni pe ki gbogbo onigbagbo tejumo ohunkohun ti won ba n se nile aye,ki won si tiraka lati mase je ki irewesi mu won, Koda ki won ma tetisi ohunkohun ti enikeni ba n so nipa won.


No comments:
Post a Comment